AroundMaps Logo
Search
Add Listing

About ADITU LAYE

ADITU LAYE,AYE ADITU,AYE AIYE,TI KO YE ENIYAN,TI ENIYAN GAN AN KO MO BI AYE TI JE,AYE OKUNKUN TI AWON ENIYAN INU RE TUN FO LOJU,AYE YOO GBE MI,IWO NKO?

Tags

Description

A gbe group yi kale lati ma fi asiri ikoko han ara wa

awon ohun to pamo fun awon kan,awon asiri ijinle lori oro aye yi,ati awa olugbe inu re.
Gege bi e ti mo wipe ko si eni to koja asise,ASISE ko mo AGBA beni ko mo OMODE,ko mo OBA beni ko mo IJOYE.

Sebi ohun ti eniyan ko ba mo,dajudaju o ju onitoun (eni na) lo.
Ohun ti iwo mo daju,ti o si ni oye pelu iriri nipa re,opolopo lo wa ti won ko mo an,ti aimo won yi si n fi iya je won baibai.

Je ki elomiran ko eko ninu ogbon ati imo pelu oye ti Olorun fi ta o lore,magbagbe pe,lojo ti eniyan ba ku,lojo na ni ogbon,imo pelu oye re yoo dake pelu re.

Iboji ni ile ebun,nibe ni awon ologbon,awon onimo pelu awon oloye ana,ti won ko fi ebun tiwon wulo fun araye ati fun Olorun wa,won ku,ebun won na si ku pelu won.
Ki iwo na to lo,ki o to fi aye yi sile,du lati fi ipa rere to se pataki lele,ni ti ogbon,ni ti imo ati ni ti oye

O MA NI GBOGBO WOLE LORUKO OLUWA,Amin.
Nitorina,ma ranti wipeee,ADITU LAYE ati awon olugbe inu AYE.

Map

Add Reviews & Rate item

Your rating for this listing :

Help Us to Improve :

Location / Contacts :